OSHE TURA

OSE OTURA Akakanika, Akakanika, Alakakanika. Alapasapa ijaka'lu, Eye kan fo feerefe o wole. Akakanika.li aape ifa, Alaka

Views 278 Downloads 217 File size 50KB

Report DMCA / Copyright

DOWNLOAD FILE

Recommend stories

Citation preview

OSE OTURA Akakanika, Akakanika, Alakakanika. Alapasapa ijaka'lu, Eye kan fo feerefe o wole. Akakanika.li aape ifa, Alakakanika li aape Odú, Alapasapa-ijaka'lu li aape Esu-Odara. Eye kan fo feerefe o wole li aape Ajé omo Olókun-sande.Oba Olubu-omi, Ógó Owoni. Esú-Odara, iwo lióte i l ú yi do. Iwo nikiijeki ebi kiopa Aiáwo i l ú . Iwo nikiijeki ebi kiopa Onísegun i l ú ; íwo nikiijeki ebi kiopa Adáhunse i l ú . Emi Aláwo ilu yi ree, Emi Adáhunse i l ú yi ree, Esu-Odara majek'ebi pa mi ati beebee. Ósétúrá Amukere (Ikere), Itekun órisa Daji, Apojojómate, Owó liaari se iyi, Owó li aari se ola, Owó li aarise odiaba lorun Olómo keririkeriri. Ósétúrá! Mimo liomoo pin; O pin fun Alará, o fi d'ade, O pin fun Ajero, o w'ewu ileke, O pin fun Oba órángún o te pa oso roja'ko. O pin fun Olúpopo Amuyun-bo'le, O pin fun Erinmagaji ehin eku jamo, O pin funOba Ado, Agbá Ilesi ad'akete pempe parí akun. O pin fun Olú-Oyinbo Am'okun sure. O pin fun Oba Ijebu Ogborogan-nida, Akoyebeyebeya'gun. O pin fun eleyo-Ajori, Ajegi-emi-san'ra, O pin fun Olomu Aperan, Olóró-agogo, O pin fun Olú Tapa lempe ododo m ajo barausa. Ojo patapata mulé d'Ekun, O pin fun Olówo Aringinjin adubule f agada ide ju'ra O pin f olówu Oduru, O pin fun Olófa Arinnolu Ayinkinni b omo le'un ati beebee. Jalao pin ni o,Esu-Odárá pin in mi o, Bara Petu pin rere fun mi.

CANTO DEL IFA PARA ASÉ Ose Otúrá Pansa ojú iná, a bara dúdú petepete Obun lo t'oko bo, lo ri siásiá D ifá fún Olúsole Ni Jo tí o nmú omi ojú sunráhún omo Igbátí yo ó bi, o bi oká O bi eré O bi opolo O bi ójólá O bi guntéré Ekó ni nse omo ikehin won lénje-lénje Ekó wá s'awo re apa ókun, ilámeji osa Igbáti yo ó dé, kó bá baba mo O ni, "Nibo ni baba lo"? Won ni baba ti sósun O wá to áwon Babaláwo lo . Won ni ebo ni kó se, pe yo ó ri baba a re Ekórú-bo Awon Babaláwo re fun ni eyo kookan ninú ohun ebo ki o lo fi bo beba re Ekó burin gáda, ó pádé ílá peki l' oná ila ni omo olóore óun, "Nibo ni ó nlo?" Ekó ni óun nwá baba lo ila fun ni ogún oké owó Ekó burin gádá, ó pádé ikán l'óna Ikán ni omo olóore oun, Nibó ni o nlo Ekó ni oun nwá baba lo Ikán fun ni ogbon oke owó Eko burin gádá, ó pádé olóbengán l'oná. Olóbengán ni omo olóore oun, Nibo ni o nlo? Ekó ni oun nwá baba lo Olóbengán fun ni ogbon oke owó Ekó tún burin gádá, ile pin niwájú, ó pin l' ehin Igbati yo ó gbé ese'kíní, gbé ese ikeji, ti yo ó gbé iketa, ó jin si agbede orun Won ni, "ogbo nrun" Baba a re ni, "ogbo kó run ." O ni, omo oun ni O ni, Kilo dé tí ó fi nwá oun bowá Ekó ni nígbátl oun dé'lé, ni wón ni ó ti wá síhiln Oni,"oká ti j'ogún oró"

O ni, ojólá ti j'ogün ohun O ni, opolo j'ogún ewu ifan o ni, "Agonsóóro j'ogún sisan" O ni wón nt ti oun bá súnmo won, áwon yo gbé oun mi Baba a re ni kó ya'nu Baba a re bá so ase kan soso ti ó ni ku, si eko ni enu O ni kó kálo O bá bere si fi gbogbo awon nkan ti eko fi rú'bo l'óde ayé háa án O ni ti eko bá dé le ayé Kí eko wi fún Won pe Ki wón pa oká ni apa dári Kí wón pa eré ni apa ládo Kí won ma fi opa teéré já iru guntéré Kí wón pa opolo, ki won ma t'ojú re bo eré O ni ti ó bádé' lé ayé TI ó bá kan odó nla tí ko bá le lo O ní ti ó bá ti fi enu so bébé ihin, yo ma bá ara re ni bebé ohún TI ó bá kan igi nla O ni tí ó bá ti fi enu so bébé ihin, yo ma bá ara re ni bebé ohún O ni ti ó bá kan óké ti kó le gun-un O ni tí ó bá ti fi enu so bébé ihin, yo ma bá ara re ni bebé ohún o ni kó di jú Ekó di'jú Baba re bá gba ni idí Ekó bá tún bá ara re I 'orí iyorin ni ibi tí ó ti ja s'óde orun ni áko'ko "Igbáti yo rin gádá, ilá lo tún ko pádé ila ni omo olóore óun niyí latí osü keta, ó ni, "O rí baba ábí o kó ri Ekó ni óun rí baba ilá ni kínni baba fun Ekó ni ó fún óun ni áse Ekó ni óun ó tile dan áse baba óun wo O ni, ilá, éwo lo ndun e ilá ni omo ni óun kó rí bi Ekó ni ki ilá ó bi ogún omo ila bi ogun omo O ni kí omo 'kookan ma ni ogboogbon omo ogoogún omo Otún pádé ikán péki O ni, "Ikán, éwo lo ndún e? Ikán ni omo ni óun kó rí bí Ekó ni ki ikán o bí ogboogbon omo, ki won ma ni áádota, ogoogún omo

rílnú Beéni ikán se bímo O tún pádé olóbengán O ni, "Olóbengán, éwo lo ndun é? Olóbengán ni omo ni óun kó rí bí Ekó ni ki olóbengán bi étalégbéje omo, ki wón ma ni ogboogbon ogoogóji omo Béeni olóbengán se bimo Ekó wá njó, ó nyó, ó nkorín O ni Bí mo duró Bí mo wúre Iré é mi kasái gba Bí mo bere, bí mo wúre ire é mi kásái gba Baba oká kú, oká jogún oró Bímo duró Bí mo wúre Iré é mi kásái gba Bi mo bere, bi mo wure iré é mi kásái gba...