Note Ejiogbe

Ejiogbe 1 Ejiogbe 1 Bi a bati ji, kamon ki olowo ori eni, Olowo ori eni laa pe’fa, Adifafun fun Ejiogbe, Nigba to nawo s

Views 206 Downloads 2 File size 37KB

Report DMCA / Copyright

DOWNLOAD FILE

Recommend stories

Citation preview

Ejiogbe 1 Ejiogbe 1 Bi a bati ji, kamon ki olowo ori eni, Olowo ori eni laa pe’fa, Adifafun fun Ejiogbe, Nigba to nawo sire gbogbo, T’owo re o to’re gbogbo, Won niko kara giri ebo nikose, O gbo riru ebo o rubo, Oni Oyeku meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Iwori meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Odi meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Irosun meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Owonrin meji moki o loni o Too too dan dan,

Baba se n fori bale fun Omo, Oni Obara meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Okanran meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Ogunda meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Osa meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Ika meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Oturupon meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Otua meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo,

Oni Irete meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Ose meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni Ofun meji moki o loni o Too too dan dan, Baba se n fori bale fun Omo, Oni eyin o mon, wipe eni toba fori bale nii nire gbogbo. Translation:. When we wake, we should praise our creator We call Ifá our creator Casted Ifá for Ejiogbe When he stretched hands to all goodness But he didn't succeed in anything He was told to do ẹbọ And he complied He said oyeku méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Iwori meji I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child

Odi meji I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Irosun méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Ọ̀wọ́nrín méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Ọ̀bàrà méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Ọkànran méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Ogunda méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Osa méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Ìkà méjì I greet you today

Too too dan dan How can a father bow down to the child Oturupon méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Otura méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Irete méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Ọ̀sẹ̀ méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Ofun méjì I greet you today Too too dan dan How can a father bow down to the child Don't you know that whoever bows down has all the goodness. Story: In this verse, ejiogbe stretched out for blessings but all his effort to make his life a better one proved abortive, he went to his Babalawo for consultation, he was told

to make sacrifices. Parts of the sacrifice that he was advised to do was to make sure to be humble enough to greet and respect everyone and he did, he woke up in the morning and went to Oyeku meji’s home to greet him. When he got there, oyeku meji was moved by this behavior that how can his elder leave his home to come and greet him at home. Then he shared his wealth with him, he left and went to iwori meji's home to greet him, iwori méjì also gave him part of his wealth. This is how ejiogbe went around all of them till he got to ofunmeji’s house which he also shared wealth with Ejiogbe. By the time ejiogbe got home to see what he’d gotten, he realised that he had gathered wealth, even more than each of them. That was how he continue to progress in his life. Ẹbọ: Eku, ẹja, abodie, àkùkọ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọtí. Akose: The person has to sacrifice his pride in this Odù. Even if he's older, he should bow down to greet everyone whether younger or older ones. Should be good to everyone and all his blessings will come to him.

Ejiogbe 2.

Aṣọ funfun ni ń sunkún aró Ipilẹ ọrọ ni ń sunkún èkejì tantantan Adífáfún ẹni olúbí Nigbati tí ń bẹ ní gbàrà esoko Wọ́n ní ẹbọ ní kowase Ó gbebo nibe ó rúbọ Ẹni olúbí kìí rahun ajé Àrìrà oko Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko Ẹni olúbí kìí rahun aya Àrìrà oko Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko Ẹni olúbí kìí rahun ọkọ Àrìrà oko Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko Ẹni olúbí kìí rahun ọmọ Àrìrà oko Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko Ẹni olúbí kìí rahun ire gbogbo Àrìrà oko Ọ̀pẹ̀ momo je ń rahun arira oko. Translation: It is the white clothes that always cry for dye The beginning of the words always cry for the next one Casted Ifá for whom the king born When he was lost and fails in life Babalawo asked him to make sacrifice and he complied whom the king born does not lack riches

Arira oko Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko whom the king born does not lack women Arira oko Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko whom the king born does not lack men Arira oko Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko whom the king born does not lack children Arira oko Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko whom the king born does not lack all goodness Arira oko Ọ̀pẹ̀, please do not let me lack, arira oko. Ẹbọ: Eku 2, ẹja 2, abodie 2, àkùkọ 2, Òkété 1. Story: Whom the king born means a child of a king, he was not supposed to be lacking in everything but after his father passed away, he began to wallow in abject poverty. He got lost in his life and doesn't know what to do to make his life meaningful anymore because he was lagging behind in everything thing. He went for consultation from babaláwo and he was told to make sacrifice which he did, akose was also done for him and things beings to be better for him after that. Akose: Èwe arira

A pack of alligator pepper, grind together and mix with Ọ̀sẹ̀. Use iyerosun to press ejiogbe on Opon Ifá (Ifá tray) and chant this verse on it. Mix with the Ọ̀sẹ̀ and use it bath every morning.

Ejiogbe 3: Eji ńlá losu lọ́mọ kékeré sure wọlé Agbaaragba ojo ni soju ọrùn dẹ̀mùdẹ̀mù Adífáfún Ọlọ́mọ weerewe òkè apa Èyí tóní ire tohun pé lọ́run Wọ́n ní kó kara giri ẹbọ ni kose Ó gbebo nibe ó rúbọ Ǹjẹ́ àtàrí mi ń gbé gba ọlá Ifá mi ń gbé gba ọmọ. Translation: It is the drizzle that made the children to rhn inside the house It's the heavy rain that made the clouds softly Casted Ifá for Ọlọ́mọ weerewe (one with small childrens) of òkè apa That said his blessings is taking long time in heaven He was told to make sacrifice and he complied

My orí is preparing wealth for me My Ifá is preparing children for me. Ẹbọ: Eku, ẹja, àkùkọ, ewúrẹ́ (she goat), Story: Ọlọ́mọ weerewe òkè apa has been making divination continuously but his prayers has not been granted all his wishes were still pending. He made consultation and he was told to make offerings to Ifá and his Ori. He was told to ask his Ori what it wants to make his wishes come true and he complied, he made the offerings to his Ifá and Orí on the same day and he did. His Ori and Ifá joined hands and brought him his goodness and blessings to him. Akose: Èwe awede, use it to wash your ikins. Put the ikins back to the container before you feed Ifa, grind the broken remaining leaves with Ọ̀sẹ̀ and use it to bath only your head before you offer your head whatever you want to use for the offerings.

Ejiogbe 4. Kaka ribiti kafibon tíì Eruku tóóró a mọ́n yọ Eruku así mọ taala bole Adífáfún Ayilegbe ọrun Nigbati ń bẹ láàrin ọ̀tá Èyí tí ó fi alapa ṣẹ́gun ọ̀tá rẹ tutu Ẹbọ lawo ni kowase Ko mọ̀n wó lota pa Ògiri alapa Ko mọ̀n wó lota pa Ògiri alapa Sàngó ń báwo rẹ ṣẹ́gun. Translation: Let's wrap it up and push it with a gun Makes dust to come out And the dust covers the day Casted Ifá for Ayilegbe ọrun When he was dining and wining with enemies And he will use old walls to conquer his enemies totally He was told to make sacrifice and he complied Let it fall on the enemies The old walls Let it fall on the enemies The old walls

Sàngó is going to conquer my enemies Ẹbọ : Eku, ẹja, abodie, àkùkọ 3, agbo (ram) Story: Unknown to Ayilegbe ọrun (the one that rolls beside ọrun) is among enemies everyday every time. They wished him bad every time and all the bad vibes reacted in his life which causes him to deteriorate in everything. He went to make consultation and he was told that his enemies is behind his misfortunes. He was told to make sacrifice and he complied with the babaláwos. One day when the enemies is planning against him beside an old wall, Èsù ọ̀dàrà made them to stand there and Sango threw his stone to the wall which fell on all of them. They all died at once and Ayilegbe ọrun begins to prosper again. Akose: Èwe ṣẹ́gun sẹ́tẹ̀ Èwe odundun Èwe tètè Bitter cola on sango Small amount of ram blood Burn everything together and grind it to make powder.

Use with cold water or ẹ̀kọ Last modified: 12:58 PM